1 Samuel 11:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo wọn bá pada lọ sí Giligali, wọ́n sì fi Saulu jọba níwájú OLUWA. Wọ́n rú ẹbọ alaafia, Saulu ati àwọn ọmọ Israẹli sì jọ ṣe àjọyọ̀ ńlá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo enia na si lọ si Gilgali; nibẹ ni nwọn gbe fi Saulu jọba niwaju Oluwa ni Gilgali: nibẹ ni nwọn gbe ru ẹbọ irẹpọ̀ niwaju Oluwa; nibẹ ni Saulu ati gbogbo awọn ọkunrin Israeli si yọ ayọ̀ nlanla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà gbogbo ènìyàn lọ sí Gílígálì, wọn sí fí Ṣọ́ọ̀lù jọba ní ìwájú OLÚWA. Níbẹ̀, ni wọn ti rú ẹbọ ìrẹ́pọ̀ ní ìwájú OLÚWA, Ṣọ́ọ̀lù àti gbogbo Ísírẹ́lì ṣe àjọyọ̀ ńlà.