1 Samuel 12:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, Samuẹli wí fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Mo ti ṣe ohun tí ẹ ní kí n ṣe. Mo ti fi ẹnìkan jọba lórí yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
SAMUELI wi fun gbogbo Israeli pe, Kiye si i, emi ti gbọ́ ohùn nyin, ninu gbogbo eyi ti ẹnyin wi fun mi, emi si ti fi ẹnikan jọba lori nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sámúẹ́lì sì wí fún gbogbo Ísírẹ́lì pé, “Èmi tí gbọ́ gbogbo ohun tí ẹ sọ fún mi, èmi sì ti yan ọba fún un yín.