1 Samuel 12:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Samuẹli bá gbadura, ní ọjọ́ náà gan-an, OLUWA sán ààrá, ó sì rọ òjò. Ẹ̀rù OLUWA ati ti Samuẹli sì ba gbogbo àwọn eniyan náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Samueli si kepe Oluwa, Oluwa si ran ãra ati ojò ni ọjọ na: gbogbo enia si bẹru Oluwa pupọ ati Samueli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Sámúẹ́lì ké pe OLÚWA, OLÚWA sì rán ààrá àti òjò ní ọjọ́ náà. Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo ènìyàn sì bẹ̀rù OLÚWA àti Sámúẹ́lì púpọ̀.