1 Samuel 12:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA kò ní ta eniyan rẹ̀ nù, nítorí orúkọ ńlá rẹ̀, nítorí pé ó wù ú láti ṣe yín ní eniyan rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti Oluwa kì yio kọ̀ awọn enia rẹ̀ silẹ nitori orukọ rẹ̀ nla: nitoripe o wu Oluwa lati fi nyin ṣe enia rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí orúkọ ńlá rẹ̀ OLÚWA kì yóò kọ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀, nítorí tí inú OLÚWA dùn láti fi yín ṣe ènìyàn rẹ̀.