1 Samuel 13:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, ní ọjọ́ ogun yìí kò sí ẹnikẹ́ni ninu àwọn ọmọ ogun Israẹli tí ó ní idà tabi ọ̀kọ̀ lọ́wọ́, àfi Saulu ati Jonatani ọmọ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li o si ṣe li ọjọ ijà, ti a kò ri idà, tabi ọ̀kọ lọwọ ẹnikẹni ninu awọn enia ti o wà lọdọ Saulu ati Jonatani; lọdọ Saulu ati Jonatani ọmọ rẹ̀ li a ri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni ọjọ́ ìjà ẹnìkankan nínú àwọn ọmọ ogun tí ó wà pẹ̀lú Ṣọ́ọ̀lù àti Jónátanì kò sì ní idà, tàbí ọ̀kọ̀ ní ọwọ́; àfi Ṣọ́ọ̀lù àti ọmọ rẹ̀ Jónátanì ni wọ́n ni wọ́n.