1 Samuel 14:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n ti farapamọ́ káàkiri agbègbè olókè Efuraimu gbọ́ pé àwọn ará Filistia ti bẹ̀rẹ̀ sí sá lọ; wọ́n yára dara pọ̀ mọ́ Saulu, wọ́n dojú ìjà kọ àwọn ọmọ ogun Filistini.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ gẹgẹ nigbati gbogbo awọn ọkunrin Israeli ti o ti pa ara wọn mọ ninu okenla Efraimu gbọ́ pe awọn Filistini sa, awọn na pẹlu tẹle wọn lẹhin kikan ni ijà na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí gbogbo àwọn Ísírẹ́lì tí ó ti pa ara wọn mọ́ nínú òkè ńlá Éfúráímù gbọ́ pé àwọn Fílístínì sá, wọ́n darapọ̀ mọ́ ìjà náà ní ìlépa gbígbóná.