1 Samuel 14:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe ṣẹgun fún àwọn ọmọ Israẹli ní ọjọ́ náà, wọ́n sì ja ogun náà kọjá Betafeni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃li Oluwa si gbà Israeli là lọjọ na: ija na si rekọja si Bet-afeni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni OLÚWA sì gba Ísírẹ́lì ní ọjọ́ náà, ìjà náà sì rékọjá sí Bẹti-Áfénì.