1 Samuel 14:40 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Saulu bá wí fún gbogbo Israẹli pé, “Gbogbo yín, ẹ dúró ní apá kan, èmi ati Jonatani, ọmọ mi, yóo dúró ní apá keji.” Wọ́n dá a lóhùn pé, “Ṣe ohun tí ó bá tọ́ lójú rẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Saulu si wi fun gbogbo awọn Israeli pe, Ẹnyin lọ si apakan, emi ati Jonatani ọmọ mi a si lọ si apakan. Gbogbo enia si wi fun Saulu pe, Ṣe eyi ti o tọ ni oju rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Ṣọ́ọ̀lù wí fún gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, “Ẹ lọ sí apá kan; èmi àti Jónátanì ọmọ mi yóò lọ sí apá kan.” Gbogbo àwọn ènìyàn sì dáhùn pé, “Ṣe èyí tí ó tọ́ ní ojú rẹ.”