1 Samuel 14:46 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn èyí, Saulu kò lépa àwọn ará Filistia mọ́. Àwọn Filistini sì pada lọ sí agbègbè wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Saulu si ṣiwọ ati ma lepa awọn Filistini: Awọn Filistini si lọ si ilu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Ṣọ́ọ̀lù sì dẹ́kun lílépa àwọn Fílístínì, àwọn Fílístínì sì padà sí ìlú wọn.