1 Samuel 16:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà Jese sọ fún Ṣama pé kí ó kọjá níwájú Samuẹli. Samuẹli tún ní, “OLUWA kò yan eléyìí náà.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jesse si mu ki Ṣamma ki o kọja. On si wipe, Oluwa kò si yàn eyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jésè sì jẹ́ kí Sámà rìn kọjá ní iwájú Sámúẹ́lì, ṣùgbọ́n Sámúẹ́lì wí pé, “OLÚWA kò yan ẹni yìí náà.”