1 Samuel 17:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ ogun Israẹli ati ti Filistini dúró ní ipò wọn, wọ́n ń wo ara wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Israeli ati Filistini si tẹgun, ogun si pade ogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ísírẹ́lì àti Fílístínì lọ sí ojú ìjà wọ́n da ojú ìjà kọ ara wọn.