1 Samuel 18:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ń ṣe àṣeyọrí nítorí pé OLUWA wà pẹlu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si ṣe ọlọgbọ́n ni gbogbo iṣe rẹ̀; Oluwa si wà pẹlu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú ohun tí ó bá ṣe, ó ń ní àṣeyọrí ńlá, nítorí tí OLÚWA wà pẹ̀lú rẹ̀.