1 Samuel 18:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn iranṣẹ náà sọ èsì tí Dafidi fún wọn fún Saulu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn iranṣẹ Saulu si wa irò fun u, pe, Ọrọ bayi ni Dafidi sọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí àwọn ìránṣẹ́ Ṣọ́ọ̀lù sọ fún un ohun tí Dáfídì sọ,