1 Samuel 18:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí wọ́n ti ń jó, wọ́n ń kọrin báyìí pé, “Saulu pa ẹgbẹẹgbẹrun tirẹ̀, ṣugbọn Dafidi pa ẹgbẹẹgbaarun tirẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn obinrin si ndá, nwọn si ngbe orin bi nwọn ti nṣire, nwọn si nwipe, Saulu pa ẹgbẹgbẹrun tirẹ̀, Dafidi si pa ẹgbẹgbarun tirẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí wọ́n ṣe ń jó, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń kọrin pé: “Ṣọ́ọ̀lù pa ẹgbẹ̀rún tirẹ̀ Dáfídì sì pa ẹgbẹgbàárún ní tirẹ̀.”