1 Samuel 19:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mikali bá sọ Dafidi kalẹ̀ láti ojú fèrèsé kan, ó sì sá lọ láti fi ara pamọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mikali si sọ Dafidi kalẹ lati oju ferese kan wá; on si lọ, o sa, o si fi ara rẹ̀ pamọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà Míkálì sì gbé Dáfídì sọ̀kalẹ̀ ó sì fi aṣọ bò ó.