1 Samuel 2:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Aláìníláárí ẹ̀dá ni àwọn ọmọ Eli mejeeji. Wọn kò bọ̀wọ̀ fún OLUWA rárá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Eli si jẹ ọmọ Beliali; nwọn kò mọ̀ Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Élì sì jẹ́ ọmọ Bélíálì; wọn kò mọ OLÚWA.