1 Samuel 2:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní gbogbo àkókò yìí, Samuẹli ń ṣe iṣẹ́ iranṣẹ sin OLUWA, ó sì jẹ́ ọmọde nígbà náà, a máa wọ ẹ̀wù efodu funfun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Samueli nṣe iranṣẹ niwaju Oluwa, o ṣe ọmọde, ti a wọ̀ ni efodi ọgbọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Sámúẹ́lì ń ṣe ìráńṣẹ́ níwájú OLÚWA, ọmọdé, ti a wọ̀ ní éfódì ọ̀gbọ̀.