1 Samuel 2:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Eli a máa súre fún Elikana ati Hana aya rẹ̀ pé, “OLUWA yóo jẹ́ kí obinrin yìí bí ọmọ mìíràn fún ọ, dípò èyí tí ó yà sọ́tọ̀ fún OLUWA.” Lẹ́yìn náà, wọn yóo pada lọ sí ilé wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eli sure fun Elkana ati aya rẹ̀ pe ki Oluwa ki o ti ara obinrin yi fun ọ ni iru-ọmọ nipa ibere na ti o bere lọdọ Oluwa. Nwọn si lọ si ile wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Élì súre fún Elikánà àti aya rẹ̀ pé, “Kí OLÚWA fún ọ ní irú-ọmọ láti ara obìnrin yìí wá, nítorí ẹ̀bùn tí ó béèrè tí ó sì tún fún OLÚWA.” Wọ́n sì lọ sí ilé wọn.