1 Samuel 2:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Samuẹli ń dàgbà sí i, ó sì ń bá ojurere OLUWA ati ti eniyan pàdé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọmọ na Samueli ndagba, o si ri ojurere lọdọ Oluwa, ati enia pẹlu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọmọ náà Sámúẹ́lì ń dàgbà, ó sì rí ojúrere lọ́dọ̀ OLÚWA, àti ènìyàn pẹ̀lú.