1 Samuel 2:34 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ọjọ́ kan náà ni àwọn ọmọ rẹ mejeeji, Hofini ati Finehasi, yóo kú. Èyí ni yóo jẹ́ àmì fún ọ pé gbogbo ohun tí mo sọ ni yóo ṣẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi li o jẹ àmi fun ọ, ti yio wá si ori ọmọ rẹ mejeji, si ori Hofni ati Finehasi, ni ọjọ kanna li awọn mejeji yio kú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Kí ni ó ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọmọ ọkùnrin rẹ̀ méjèèjì, Hófínì àti Fínéhásì, yóò jẹ́ àmì fún ọ, àwọn méjèèjì yóò kú ní ọjọ́ kan náà.