1 Samuel 20:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
má jẹ́ kí àánú rẹ kúrò ninu ilé mi títí lae. Nígbà tí OLUWA bá ti ké gbogbo àwọn ọ̀tá Dafidi kúrò lórí ilẹ̀ ayé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn ki iwọ ki o máṣe mu ãnu rẹ kuro ni ile mi lailai: ki isi ṣe igbati Oluwa ke olukuluku ọtá Dafidi kuro lori ilẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má ṣe ké àánú rẹ kúrò lórí ìdílé mi títí láé. Bí OLÚWA tilẹ̀ ké gbogbo ọ̀ta Dáfídì kúrò lórí ilẹ̀.”