1 Samuel 20:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
má jẹ́ kí orúkọ Jonatani di ìkékúrò ní ilé Dafidi. Kí OLUWA gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá Dafidi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ ni Jonatani bá ile Dafidi da majẹmu wipe, Oluwa yio si bere rẹ̀ lọwọ awọn ọta Dafidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Jónátanìf bá ilé Dáfídì dá májẹ̀mú wí pé, “OLÚWA yóò pe àwọn àti Dáfídì láti sírò”