1 Samuel 20:39 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
kò mọ nǹkankan; Jonatani ati Dafidi nìkan ni wọ́n mọ ìtumọ̀ ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọmọdekunrin na kò si mọ̀ nkan: ṣugbọn Jonatani ati Dafidi li o mọ̀ ọ̀ran na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
(Ọmọdékùnrin náà kò sì mọ̀ nǹkan; ṣùgbọ́n Jónátanì àti Dáfídì ni ó mọ ọ̀ràn náà.)