1 Samuel 23:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí Dafidi gbọ́ pé àwọn ará Filistia ń gbógun ti àwọn ará Keila, wọ́n sì ń jí ọkà wọn kó ní ibi ìpakà,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NWỌN si wi fun Dafidi pe, Sa wõ awọn ara Filistia mba ara Keila jagun, nwọn si jà ilẹ ipakà wọnni li ole.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì wí fún Dáfídì pé, “Ṣá wò ó, àwọn ará Fílístínì ń bá ará Kéílà jagun, wọ́n sì ja àwọn ilẹ̀ ìpakà lólè.”