1 Samuel 23:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀rù ba Dafidi nítorí pé Saulu ń wá ọ̀nà láti pa á. Dafidi ń gbé aṣálẹ̀ Sifi ni Horeṣi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si ri pe, Saulu ti jade lati wá ẹmi on kiri: Dafidi si wà li aginju Sifi ninu igbo kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì ríi pé, Ṣọ́ọ̀lù ti jáde láti wá ẹ̀mi òun kiri: Dáfídì sì wà ní ihà Sífì nínú igbó kan.