1 Samuel 23:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn mejeeji dá majẹmu níwájú OLUWA; Dafidi dúró ní Horeṣi, Jonatani sì pada sílé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn mejeji si ṣe adehun niwaju Oluwa; Dafidi si joko ninu igbo na. Jonatani si lọ si ile rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn méjèèjì sì ṣe àdéhùn níwájú OLÚWA; Dáfídì sì jókòó nínú igbó náà. Jónátanì sì lọ sí ilé rẹ̀.