1 Samuel 24:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dafidi bá búra fún Saulu. Saulu ati àwọn eniyan rẹ̀ pada sílé, Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ sì pada sí ibi tí wọ́n sá pamọ́ sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si bura fun Saulu. Saulu si lọ si ile rẹ̀; ṣugbọn Dafidi ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ si goke lọ si iho na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì búra fún Ṣọ́ọ̀lù. Ṣọ́ọ̀lù sì lọ sí ilé rẹ̀; ṣùgbọ́n Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì gòkè lọ sí ihò náà.