1 Samuel 25:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn tí Dafidi rán dé ibẹ̀, wọ́n jíṣẹ́ fún Nabali, ní orúkọ Dafidi, wọ́n sì dúró.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọkunrin Dafidi si lọ, nwọn si sọ fun Nabali gẹgẹ bi gbogbo ọ̀rọ wọnyi li orukọ Dafidi, nwọn si simi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọkùnrin Dáfídì sì lọ, wọ́n sì sọ fún Nábálì gẹ́gẹ́ bí gbogbo ọ̀rọ̀ wọ̀nyí ní orúkọ Dáfídì, wọ́n sì sinmi.