1 Samuel 26:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Má jẹ́ kí n kú sílẹ̀ àjèjì níbi tí OLUWA kò sí. Kí ló dé tí ọba Israẹli fi ń lépa èmi kékeré yìí, bí ẹni ń dọdẹ àparò lórí òkè?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ máṣe jẹ ki ẹjẹ mi ki o ṣàn silẹ niwaju Oluwa: nitori ọba Israeli jade lati wá itapin bi ẹni ndọdẹ aparo lori oke-nla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ má ṣe jẹ́ kí ẹ̀jẹ̀ mi ó ṣàn sílẹ̀ níwájú OLÚWA; nítorí ọba Ísírẹ́lì jáde láti wá ẹ̀mí mi bi ẹni ń dọdẹ àparò lórí òkè ńlá.”