1 Samuel 26:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Dafidi lọ lẹsẹkẹsẹ láti rí ibi tí Saulu ati Abineri, ọmọ Neri, olórí ogun Saulu, dùbúlẹ̀ sí. Saulu wà ninu àgọ́, àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sì pàgọ́ yí i ká.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si dide, o si wá si ibi ti Saulu pagọ si: Dafidi si ri ibi ti Saulu gbe dubulẹ si, ati Abneri ọmọ Neri, olori ogun rẹ̀: Saulu si dubulẹ larin awọn kẹ̀kẹ́, awọn enia na si pagọ wọn yi i ka.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì dìde, ó sì wá sí ibi ti Ṣọ́ọ̀lù pàgọ́ sí: Dáfídì rí ibi tí Ṣọ́ọ̀lù gbé dúbúlẹ̀ sí, àti Ábínérì ọmọ Nérì, olórí ogun rẹ̀: Ṣọ́ọ̀lù sì dùbúlẹ̀ láàrin àwọn kẹ̀kẹ́, àwọn ènìyàn náà sì pàgọ́ wọn yí i ká.