1 Samuel 27:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n ń gbé Gati pẹlu àwọn ará ilé wọn. Àwọn aya Dafidi mejeeji, Ahinoamu ará Jesireeli ati Abigaili ará Kamẹli, opó Nabali, sì wà pẹlu rẹ̀ níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si ba Akiṣi joko ni Gati, on, ati awọn ọmọkunrin rẹ̀, olukuluku wọn ti on ti ara ile rẹ̀; Dafidi pẹlu awọn aya rẹ̀ mejeji, Ahinoamu ara Jesreeli, ati Abigaili ara Karmeli aya Nabali.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì bá Ákíṣì jókòó ní Gátì, òun, àti àwọn ọmọkùnrin rẹ, olúkúlùkù wọn pẹ̀lú ará ilé rẹ̀; Dáfídì pẹ̀lú àwọn aya rẹ̀ méjèèjì, Áhínóámù ara Jésréélì, àti Ábígáílì ará Kámẹ́lì aya Nábálì.