1 Samuel 27:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Akiṣi fún un ní ìlú Sikilagi, nítorí náà ni Sikilagi fi jẹ́ ti àwọn ọba Juda títí di òní yìí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Akiṣi si fi Siklagi fun u ni ijọ na; nitorina ni Siklagi fi di ti awọn ọba Juda titi o fi di oni yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ákíṣì sí fi Síkílágì fún un ní ijọ́ náà nítorí náà ni Síkílágì fí dí ọba Júdà títí ó fí dì òní yìí.