1 Samuel 29:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àbí nítorí Dafidi yìí kọ́ ni àwọn ọmọbinrin Israẹli ṣe ń jó tí wọ́n sì ń kọrin pé, ‘Saulu pa ẹgbẹẹgbẹrun tirẹ̀, ṣugbọn Dafidi pa ẹgbẹẹgbaarun tirẹ̀?’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣe eyi ni Dafidi ti nwọn tori rẹ̀ gberin ara wọn ninu ijo wipe, Saulu pa ẹgbẹgbẹrun rẹ̀, Dafidi si pa ẹgbẹgbãrun tirẹ̀?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣé èyí ni Dáfídì ti wọn torí rẹ̀ gberin ara wọn nínú ìjọ wí pé, “ ‘Ṣọ́ọ̀lù pa ẹgbẹgbẹrun rẹ̀, Dáfídì si pa ẹgbẹgbàárun tirẹ́.’ ”