1 Samuel 29:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, jọ̀wọ́ pada ní alaafia, kí o má baà múnú bí wọn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ yipada ki o si ma lọ li alafia, ki iwọ ki o má ba ṣe ibanujẹ fun awọn Filistini.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ yípadà kí o sì máa lọ ní àlàáfíà, kí ìwọ má ṣe bà àwọn Fílístínì nínú jẹ́.”