1 Samuel 30:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí Dafidi ati àwọn ọkunrin rẹ̀ pada dé Sikilagi ní ọjọ́ kẹta, wọ́n rí i pé àwọn ará Amaleki ti gbógun ti Nẹgẹbu ati Sikilagi, wọ́n ṣẹgun Sikilagi, wọ́n sì sun ìlú náà níná;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, nigbati Dafidi ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ si bọ̀ si Siklagi ni ijọ kẹta, awọn ara Amaleki si ti kọlu iha ariwa, ati Siklagi, nwọn si ti kun u;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì ṣe nigbà ti Dáfídì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì bọ̀ sí Síkílágì ní ọjọ́ kẹta, àwọn ará Ámálékì sì ti kọlu Néséfà, àti Síkílágì, wọ́n sì ti kùn ún ní iná.

Recommended Reading