1 Samuel 30:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Dafidi sì gba àwọn eniyan rẹ̀ pada, ati gbogbo nǹkan tí àwọn ará Amaleki náà kó, ati àwọn iyawo rẹ̀ mejeeji.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dafidi si gba gbogbo nkan ti awọn ara Amaleki ti ko: Dafidi si gbà awọn obinrin rẹ̀ mejeji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dáfídì sì gbà gbogbo nǹkan tí àwọn ará Ámálékì ti kó: Dáfídì sì gba àwọn obìnrin rẹ̀ méjèèjì.