1 Samuel 4:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n gba àpótí ẹ̀rí Ọlọrun lọ́wọ́ àwọn ọmọ Israẹli, wọ́n sì pa Hofini ati Finehasi, àwọn ọmọ Eli mejeeji.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si gbà apoti ẹri Ọlọrun: ọmọ Eli mejeji si kú, Hofni ati Finehasi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n gba àpótí ẹ̀rí OLÚWA, àwọn ọmọkùnrin Élì méjèèjì sì kú, Hófínì àti Fínéhásì.