1 Samuel 4:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọkunrin náà wí fún un pé, “Ojú ogun ni mo ti sá wá lónìí.” Eli bá bi í pé, “Kí ló dé, ọmọ mi?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọkunrin na si wi fun Eli pe, Emi li ẹniti o ti ogun wá, loni ni mo sa ti ogun na wá; o si bi i pe, Eti ri, ọmọ mi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọkùnrin náà sọ fún Élì, “Mo ṣẹ̀ ṣẹ̀ dé láti ibi ogun náà ni: mo sá láti ibi ogun náà wá lónìí.” Élì sì béèrè pé, “Kí ni ó ṣẹlẹ̀ ọmọ mi?”