1 Samuel 5:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ara gbogbo àwọn tí kò kú ninu wọn kún fún kókó ọlọ́yún. Ariwo àwọn eniyan náà sì pọ̀ pupọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọkunrin ti kò kú ni a si fi iyọdi pọn loju: igbe ilu na si lọ soke ọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí kò kú wọ́n pọ́n wọn lójú pẹ̀lú àrùn oníkókó, ẹkún ìlú náà sì gòkè lọ sí ọ̀run.