1 Samuel 6:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n gbé àpótí OLUWA sinu kẹ̀kẹ́ ẹrù náà, pẹlu àpótí tí wọ́n kó àwọn èkúté wúrà ati kókó ọlọ́yún wúrà náà sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn gbe apoti Oluwa wa lori kẹkẹ́ na, apoti pẹlu ẹ̀liri wura na, ati ere iyọdí wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí OLÚWA lé orí kẹ̀kẹ́ ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ni àpótí tí eku ẹ̀lírí wúrà àti àwòrán àrùn oníkókó wà níbẹ̀.