1 Samuel 6:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọba Filistini ń wò wọ́n bí wọ́n ti ń ṣe, lẹ́yìn náà, wọ́n yipada sí ìlú Ekironi ní ọjọ́ náà gan-an.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn ijoye Filistini marun si ri i, nwọn tun yipada lọ si Ekroni li ọjọ kanna,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn aláṣẹ Fílístínì márààrún rí gbogbo èyí, wọ́n sì padà ní ọjọ́ náà sí Ékírónì.