1 Samuel 6:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ará ìlú Beti Ṣemeṣi ní, “Ta ló lè dúró níwájú OLUWA Ọlọrun mímọ́ yìí? Ọ̀dọ̀ ta ni yóo fẹ́ lọ, tí yóo fi kúrò lọ́dọ̀ wa?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọkunrin Betṣemeṣi si wipe, Tani yio le duro niwaju Oluwa Ọlọrun mimọ́ yi? ati lọdọ tani yio lọ bi o kuro lọdọ wa?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọkùnrin ará Bẹti-Sémésì béèrè pé, “Ta ni ó le è dúró ní iwájú OLÚWA Ọlọ́run mímọ́ yìí? Ọ̀dọ̀ ta ni àpótí ẹ̀rí OLÚWA yóò gbà gòkè lọ láti ibí yìí?”