1 Samuel 7:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, yóo pada lọ sí ilé rẹ̀, ní Rama, nítorí pé a máa dájọ́ fún àwọn eniyan níbẹ̀ pẹlu. Ó sì tẹ́ pẹpẹ kan sibẹ fún OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On a si ma yipada si Rama: nibẹ ni ile rẹ̀ gbe wà; nibẹ na li on si ṣe idajọ Israeli, o si tẹ pẹpẹ nibẹ fun Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ó máa ń padà sí ilé rẹ̀ ní Rámà, níbí, ó sì tún ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì níbẹ̀, ó sì kọ́ pẹpẹ kan ṣíbẹ̀ fún OLÚWA.