1 Samuel 9:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Saulu bá dá a lóhùn pé, “O ṣeun, jẹ́ kí á lọ.” Wọ́n bá lọ sí ìlú tí eniyan Ọlọrun yìí wà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Saulu wi fun iranṣẹ rẹ̀ pe, Iwọ wi rere; wá, jẹ ki a lọ. Bẹ̃ni nwọn si lọ si ilu na nibiti ẹni Ọlọrun nã gbe wà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣọ́ọ̀lù sọ fún ìránṣẹ́ ẹ rẹ̀ pé ó dára “Jẹ́ kí a lọ” Wọ́n jáde lọ sí ìlú tí ènìyàn Ọlọ́run náà ń gbé.