1 Samuel 9:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí wọ́n ti ń gun òkè lọ láti wọ ìlú, wọ́n pàdé àwọn ọmọbinrin tí wọ́n ń jáde lọ pọn omi. Wọ́n bi àwọn ọmọbinrin náà pé, “Ǹjẹ́ aríran wà ní ìlú?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi nwọn ti nlọ si oke ilu na, nwọn ri awọn wundia ti nlọ fa omi, nwọn bi wọn lere wipe, Arina mbẹ nihin bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí wọ́n ṣe ń lọ ní orí òkè sí ìlú náà, wọ́n pàdé àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin tí ó ń jáde í bọ̀ láti wá pọn omí. Wọ́n sì bi wọ́n, “Ṣé wòlíì náà wà níbí?”