1 Samuel 9:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Saulu ati iranṣẹ rẹ̀ bá gòkè wọ ìlú lọ. Bí wọ́n ti ń lọ, wọ́n rí Samuẹli tí ń jáde bọ̀ wá sí ọ̀nà ọ̀dọ̀ wọn, ó ń lọ sí orí òkè tí wọ́n ti ń rúbọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn goke lọ si ilu na: bi nwọn si ti nwọ ilu na, kiye si i, Samueli mbọ̀ wá pade wọn, lati goke lọ si ibi giga na,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n gòkè lọ sí ìlú náà, bí wọ́n ti ń wọlé, níbẹ̀ ni Sámúẹ́lì, ń bọ̀ wá sí ọ̀dọ̀ wọn bí ó ti ń lọ ibi gíga náà.