1 Samuel 9:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Samuẹli bá mú Saulu ati iranṣẹ rẹ̀ wọ inú gbọ̀ngàn ńlá lọ, ó fi wọ́n jókòó sí ààyè tí ó ṣe pataki jùlọ níbi tabili oúnjẹ tí wọ́n fi àwọn àlejò bí ọgbọ̀n jókòó sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Samueli si mu Saulu ati iranṣẹ rẹ̀, o si mu wọn wọ inu gbàngàn, o si fun wọn ni ijoko lãrin awọn agbagba ninu awọn ti a pè, nwọn si to ọgbọ̀n enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni Sámúẹ́lì mú Ṣọ́ọ̀lù pẹ̀lú ìránṣẹ́ rẹ̀ wọ inú gbọ̀ngàn, ó sì mú wọn jókòó sí iwájú àwọn tí a pè—tí wọn tó ọgbọ̀n.