1 Samuel 9:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ wá sinu ìlú láti ibi ìrúbọ náà, wọ́n tẹ́ ibùsùn kan fún Saulu lórí òrùlé, ó sì sùn sibẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati nwọn sọkalẹ lati ibi giga nì wá si ilu, Samueli si ba Saulu sọrọ lori orule.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn ìgbà tí wọn ti sọ̀kalẹ̀ láti ibí gíga náà wá sí inú ìlú, Sámúẹ́lì sì bá Ṣọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ lórí òrùlé ilé e rẹ̀.