1 Samuel 9:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ Kiṣi, baba Saulu sọnù. Kiṣi bá sọ fún Saulu ọmọ rẹ̀ pé, “Mú ọ̀kan ninu àwọn iranṣẹ lẹ́yìn, kí ẹ lọ wá àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà wá.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kẹtẹkẹtẹ Kiṣi baba Saulu si nù. Kiṣi si wi fun Saulu ọmọ rẹ̀ pe, Jọwọ mu ọkan ninu awọn iranṣẹkunrin pẹlu rẹ ki o si dide lọ wá kẹtẹkẹtẹ wọnni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nísinsìn yìí àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí ó jẹ́ ti Kíṣì baba Ṣọ́ọ̀lù sì sọnù. Nígbà náà, Kíṣì sọ fún Ṣọ́ọ̀lù ọmọ rẹ̀ pé, “Mú ọ̀kan nínú àwọn ìránṣẹ́ pẹ̀lú rẹ kí ẹ lọ láti wá àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà.”