1 Thessalonians 2:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí tí kò bá ṣe ẹ̀yin, ta tún ni ìrètí wa, ayọ̀ wa, ati adé tí a óo máa fi ṣògo níwájú Oluwa wa Jesu nígbà tí ó bá farahàn?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori kini ireti wa, tabi ayọ̀ wa, tabi ade iṣogo wa? kì ha iṣe ẹnyin ni niwaju Jesu Oluwa wa ni àbọ rẹ̀?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ni ìrètí wa, ayọ̀ wa, tàbí adé wa nínú èyí tí a ó sògo níwájú Jésù Olúwa nígbà tí òun bá dé? Ṣé ẹ̀yin kọ ní?